Olubukola Anifowose – “ÌYÈ RÉ” (This Is Life) ||

Olubukola Anifowose, the Nigerian-born US-based gospel singer and  prolific song-writer comes up with a new release single titled “ÌYÈ RÉ (This Is Life)”

“ÌYÈ RÉ (This is life)” is a song of gratitude for the life we’ve received through God’s grace.  In every breath, in every step, we’re alive in Him. His love is our heartbeat, His mercy is our guide. This is the true essence of life!

John 10:10 – The thief comes to steal, kill, and destroy; I have come that they may have life and have it to the full.

Jesus is the life-giver. He gives hope, joy, and peace.

Watch Video Below;

STREAM MP3

Lyrics: ÌYÈ RÉ (This Is Life) – Olubukola Anifowose

Lead: Oro Olorun
Iye ni
Iye ni
Titi aye o
Iye ni
Titi lai
Iye ni X3

Eni ba Gbagbo
Bo ti le ku
Yi o ye titi lai
Yi o titi lai
Titi aye o
Iye ni X2

Elese (Gba-a-gbo)
O ri igbala o
Titi lai
Igbala o
Lodo Jesu igbala o
Titi lai igbala o

Elese gba-a-gbo
Ori igbala o
Titi lai
Igbala o
Lodo Jesu
Igbala o

Iye e e e
Iye ainipekun

Lead: Aditi gba-gbo
O ti iwosan o
Titi lai
Iwosan o
Lodo Jesu
Titi Aye o X2

Bridge: Iye ni wiwo
Eni ta kan mo gi
Iye wa nisisinyi fun o
Iye ni wiwo
Eni ta kan mo gi
Iye wa nisinsinyi fun o

Ore mi
Iye ni
Titi lai
Iye, iye, iye
Iye ni
Titi lai
Iye ainipekun
Iye ni titilai
Ore mi jowo wa
Iye ni titi lai
Ma ma se je o pe
Iye ni iye ni
Ola le peju fun o
Iye ni, iye ni
Husile ni o
Iye ni, titi lai

Bridge: O ti to Jesu
F’agbara iwenu mo
a we o ninnu eje Od;aguntan
Iwo a gbekele Ore’ofe re
A we o ninu eje Od’agutan

Lead: Se a ti we o sa ti we o
Ninu eje e e
Ninu eje tinwe okan mo
S’aso re a fun fun
Yo si mo laulau

Awe o ninu eje Od’aguntan
Ore mi

Se ati we o
Ninu eje
Ninu eje ti n we Okan mo
S’aso re a funfun
Yo si mo laulau

A we o ninu eje Od’agutan

Adlib: Ore mi
Iye ni
Titi lai, Iye ni
Idande ni o
Iye ni titi lai iye ni
Mama je o pe
Iye ni titi lai iye ni

Od’agutan ti a apa
Iye ni titi lai iye ni
O fe je pese re
Iye ni titi lai iye ni
Eje Iye ni
Eje Iyebiye
Iye ni titi lai iye ni
Mo ti towo mo ti ri
Iye ni titi lai iye ni

Oyin ni, oyin ni oyin ni
Iye ni titi lai iye ni
Iye e e, iye ni
Iye e e
Iye e e, ie ni
Titi lai
Latodo Jesu
Iye ni titi lai

Ore ma bo o
Iye ni titi lai
Iye iye iye
Iyeni titi lai
Idande ni o
Iye ni
Titi lai
Iye ni

Credits:
Songwriter: Olubukola Anifowose
Producer: Abbey Sound Studio

Connect:
Instagram: https://www.instagram.com/ogunfoworaanifowose/
Facebook: https://facebook.com/olubukolaogunfowora.anifowose
TikTok: https://www.tiktok.com/@olubukolaogunfowora

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *