AUDIO: Victor Vincent – ”Ise Owo Re” | Feat. Blessing Surulere | @victorvincent84 |

SECRET PLACE RECORDS recording gospel artist, Minstrel Victor Vincent releases new single from his upcoming album CELESTIAL WORSHIP. He features dynamic singer Blessing Surulere a lead singer at City of God Faith Ministries  in Lagos, Nigeria on this song which was produced by Micheal Bassey.

He titles this song ” ISE OWO RE ” meaning “THE WORKS OF YOUR HANDS”.

Download

LYRICS

ISE OWO RE.

(Yoruba Praise chant to the Almighty God)

BLESSING:-

Kabiesi iba re ooo

Ise owo re, gbin gbin nii

Mo roo ti ti, mii oku le roo tan

Oba to da orun, ti ofi opo gbe duro

Alapa nla to so ile aiye roo

Oba to da imole ti osi gba agbara lowo orun tabi osupa

Olulana, olutana, oludari aiye ati orun

Moma riii ise owo re o oluwa.

VICTOR:-

Oba, oba

Oba aiye raiye, mori ise owo re (x2)

Iyin ati ope lo yee oo

Mori ise owo re(x2)

BACKUPS :-

Oba, oba

Oba aiye raiye, mori ise owo re (x2)

Iyin ati ope lo yee oo

Mori ise owo re(x2)

MODULATION

(Call$Resp)

VICTOR:-  Laiye lorun, haa kee hallelujah

BACK UPS:-Aari ise owo re 

(x4)

BRIDGE

BACK UP:-Oba, awon oba

Mofi iyin fun oo nikan.

(Yoruba Praise Chant to the Almighty God )

BLESSING:-

Oba ti oro re ju ogun loo

Oba ari ibi, ri ogun, ri ala

Okan shosho ajanaku tii mii aiye ati orun

Oba tin fi eja se ile fun Jonah, to sii so di oko losi taasisi

Sebi Iwo noni olulana to Lana fun Elijah lati aiye yii lode orun

Awa ma gboriyin fun oruko ree oo

Ise owo re oni idiwon

Olulana, olutana, oludari aiye ati orun

Oba tin paaa agan lerin lojosi

Eni ipinle

Eni opin

Eni isaaju

Eni ikeyin

Eni ma gbori yin fun oruko re oooo.

VICTOR:-

Oba, oba

Oba aiye raiye, mori ise owo re (x2)

Iyin ati ope lo yee oo

Mori ise owo re(x2)….End….

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *